adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/01.txt

1 line
261 B
Plaintext

\c 15 \v 1 Ni aaro kutukutu, awon olori alufa pelu awon agbagba ati akowe ati gbogbo Igbimo awon Jew. Won so Jesu, won si mu lo. Won fi le Pilatu lowo. \v 2 Pilatu bii, "Se iwo ni oba awon Jew?" O dalohun, "Iwo wi." \v 3 Awon Olori Alufa nfi esu pupo kan Jesu.