adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/39.txt

1 line
335 B
Plaintext

\v 39 Nigbati Ogagun ogorun tio duro koju si Jesu ri pe o ti ku, o wipe, "Nitooto, omo Olorun ni okunrin yi." \v 40 Awon obinirin wani ibe, won si ti wo lati okankan. Ninu won ni Maria Magdaleni, Maria (iya Jakobu kekere ati Jose), ati Salomi. \v 41 Nigbati ti o wa ni Galili, won tele lati sin. Awon obinrin miran tele wa Jerusalemu.