adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/14.txt

1 line
268 B
Plaintext

\v 14 Pílátù sì wí fún wọn, "Kíni aìda tó se?" Sùgbọ́n wọ́n tún pariwo sókè, "Kàán mọ́ àgbélèbú." \v 15 Pílátù fẹ́ tẹ́ awon ero na lorun, nitorina, he fi Baraba sile fun won. Ofi naa Jesu, osi fi le won lowo lati kan mo agbelebu.