adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/16.txt

1 line
209 B
Plaintext

\v 16 Awon omo ogun si mu wo inu ile ejo, wonsi pe gbogbo awon omo ogun iyoku \v 17 Won fi aso igunwa elese aluko wo, wonsi hun ade egun, wonsi fi de ni ori \v 18 Won bere si juba re pe "Iba o, Oba awon Jew!"