adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/09.txt

1 line
219 B
Plaintext

\v 9 Pilatu dawon lohun wipe, "Se efe ki emi fi Oba awon Jew sile ni?" \v 10 Nitori o mo pe awon olori alufa fi le oun lowo nitori owu \v 11 Sugbon awon olori alufa ru awon ero soke lati pariwo pe Baraba ni kio fi sile.