adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/21.txt

1 line
401 B
Plaintext

\v 21 Jésù wí fún wọn pé, “A ha lè gbé fìtílà wọ inú ilé láti fi sábẹ́ agbọ̀n tàbí sábẹ́ àkéte? a o gbé e ka orí ọ̀pá fìtílà ni. \v 22 Nítorí kò sí ohun tí ó pamọ́ tí a kò ní fihàn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ohun tí ó wà ní ìkọ̀kọ̀, tí kò ní wá sí gbangba. \v 23 Bí ẹnikẹ́ni bá ní etí láti fi gbọ́, kí ó gbọ́!”