adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/16.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 16 Èyí ni àwọn tí ó bọ́ sórí àpáta, nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ọrọ̀ náà, lójúkanánáà wọ́n fi ayọ̀ gbà á. \v 17 Ṣùgbọ́n wọn kò ni gbòǹgbò nínú u wọn, Ṣùgbọ́n wọ́n faradàá fún ìgbà díẹ̀. Lẹ́yìn náà ni wàhálà tàbí inúnibíni dìde nítorí ọ̀rọ̀ náà, lójúkan náà, wọ́n subú.