adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/03.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 3 “Ẹ fi etí sílẹ̀, afúnrúgbìn náà jáde lọ láti lọ fúnrúgbìn rẹ̀. \v 4 Bí ó ti ń fúnrúgbìn, díẹ̀ bọ́ sí ẹ̀bá ọ̀nà, àwọn ẹyẹ sì wá, wọ́n sì ṣà á jẹ. \v 5 Díẹ̀ bọ́ sórí ilẹ̀ àpáta, níbi tí erùpẹ̀ ko sí púpọ̀. Lójúkannáà ó hu jáde, nítorí wọn kò ní erùpẹ̀ púpọ̀.