adesinaabegunde_yo_mrk_text.../04/01.txt

1 line
295 B
Plaintext

\c 4 \v 1 Ó tún bẹ̀rẹ̀ sí ń kọ́ni létí òkun, ọpọ̀ ènìyàn si yíi ká. Ó bọ́ sínú ọkọ̀ ojú omi tí ó wà lórí òkun, àwọn ènìyàn sì wà ní étí òkun. \v 2 Ó kọ́ wọn ní ohun púpọ̀ pẹ̀lú òwe, ẹ̀yí ni ojun tí ó wí fún wọn.