adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/35.txt

1 line
298 B
Plaintext

\v 35 Ó sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀, kí ilẹ̀ tó mọ́, Ó kúrò ó sì lọ sí ibi tí ó dákẹ̀ láti lọ gbàdúrà. \v 36 Símónì àti àwọn tí ó wà pẹ́lu rẹ̀ lọ láti wá a. \v 37 Wọ́n rí I wọ́n sì wí fún pé, “Gbogbo ènìyàn ń wá ọ!”