adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/45.txt

1 line
459 B
Plaintext

\v 45 Nígbàtí Pílátù gbọ́ láti ọ̀dọ ọ̀gágun-ọgọ̀rún pé Jésù ti kú, ó yọ̀ǹda ara rẹ̀ fún Jósẹ́fù \v 46 Jóséfù sì ti ra asọ dídán kan. Ó gbe sọ̀kalẹ̀ láti orí àgbélèbú, ó fi asọ náà wée, ó sì tẹ sí inú ibojì tí a ti gbẹ́ nínú àpáta. Nígbà náà, ó yí òkúta sí ẹnu ọ̀nà ibojì náà \v 47 Maria Magdaleni àti Maria ìya Jósè sì rí ibi tí a sin Jésù sí.