adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/39.txt

1 line
465 B
Plaintext

\v 39 Nígbàtí Ọ̀gágun ọgọ̀rún tí ó dúró kojú sí Jésù ri pé ó ti kú, ó wípé, "Nítòótọ́, ọmọ Ọlọ́run ni ọkùnrin yíí." \v 40 Àwọn obìnirin tí n wò láti ọ̀kánkán wànì ibẹ̀. Nínú wọn ni Maria Magdaleni, Maria (ìya Jákọ́bù kékerè àti Jósè), àti Sàlómì. \v 41 Nígbàtí ó wà ní Galili, wọ́n tẹ̀le láti sìn. Àwọn obìnrin míràn sì tẹ̀lee wá sí Jerusalemu pẹ̀lú.