adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/36.txt

1 line
365 B
Plaintext

\v 36 Ẹnìkan sáré láti fí ọtí kíkan sí orí fùkẹ̀fùkẹ̀, wón fi sí orí ọ̀pá, wọ́n sì fi fun láti mu. Ọkùnrin náà wípé, "Ẹjẹ́ kí á wòó bóyá Èlíjà yó wá múu sọ̀kalẹ̀." \v 37 Jésù sì kígbe lóhùn rara, ósì kú \v 38 Asọ ìkéle tẹ́mpílí sì fàya sí méjì láti òkè títí dé ìsàlẹ̀.