1 line
406 B
Plaintext
1 line
406 B
Plaintext
\v 28 Lootọ ni mo wí fun yín, gbogbo ẹ̀sẹ̀ àwọn ọmọ ènìyàn li ó ní ìdáríjì ati àwọn ọ̀rọ̀ òdì tí wọ́n sọ jáde, \v 29 sùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí o bá sọ̀rọ̀ òdì tako ẹ̀mí mímọ́ ki yíò ri ìdáríjì gba lailai sùgbọ́n ó jẹ̀bi ẹ̀sẹ̀ ayérayé \v 30 Jésù sọ ǹkan yí nítorípé wọ́n sọ pé "Ó ní ẹ̀mí aìmọ́" |