|
\v 5 Jésù rí ìgbàgbọ́ wọn, Ó sì wí fún ọkùnrin arọ náà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wé sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn: \v 7 "Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?" |