adesinaabegunde_yo_mrk_text.../01/23.txt

1 line
582 B
Plaintext

\v 23 Nígbànáà ọkùnrin kan tí ó wà nínú Sínágọ́gù wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe, \v 24 wí pé, “Kí ni àwa ní se pèlu rẹ, Jésù ti Násárẹ́tì? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!” \v 25 Jesu si bá èmí èsù náà wí, ó wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́, kí ó sì jáde kúrò lára rẹ̀!.” \v 26 Ẹ̀mí àìmọ́ náà sì gbé e sánlè, ó sì jáde kúrò lára ọkùnrin náà bí ó ti ń ké ní ohùn rara.