adesinaabegunde_yo_mrk_text.../06/14.txt

1 line
348 B
Plaintext

\v 14 Ọba Ẹ́rọ́dù sì gbọ́, nítorí ìròyìn Jésù tàn ká. Àwọn kán nwípé "Jòhánà Onítẹ̀bọmi ti jí dìde, ìdí nìyí tí isẹ́ agbára fí nsẹlẹ̀ láti ọwọ́ rẹ̀. \v 15 Àwọn míràn sì wípé"Èlíjà ni." Bẹ́ẹ̀ ni àwọn míràn sì wípé "ọ̀kan nínú àwọn wǒlí àtijọ́ ni."