adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/33.txt

1 line
310 B
Plaintext

\v 33 Ni gba tio di wakati kefa ojo, okunkun bo gbogbo ile titi di wakati kesan \v 34 Ni igba ti o di wakati kesan, Jesu pariwo ni ohun rara, "Eloi, Eloi, lama sabachthani?" eyi tio tun mo si "Olorun mi, Olorun mi, kilode ti iwo ko mi si le?" \v 35 Awon tio duro gbo oro wonyi, won si wipe, "wo, oun pe Elija"