adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/19.txt

1 line
372 B
Plaintext

\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú opa, won si tu to si oju. Won kunle ni waju re bii pe won juba re. \v 20 Nigbati won ti se eleya re, won bo aso igunwa elese aluko naa, wonsi fi aso re wo, won si muu lo lati kan mo agbelebu \v 21 Won fi ipa mu enikan ton koja lo leba ona lati gbe agbelebu Jesu, okunrin ti a npe oruke re ni Simoni ara Kireni, baba Alesanda ati Rufusi.