adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/09.txt

1 line
305 B
Plaintext

\v 9 Pílátù dawọn lóhùn wípé, "Sé ẹfẹ̀ kí èmi fi Ọba àwọn Júù sílẹ̀ ni?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfa fi lé òun lọ́wọ́ nítorí owú \v 11 Sùgbọ́n àwọn olórí àlùfa ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kíó fi sílẹ̀.