adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/42.txt

1 line
286 B
Plaintext

\v 42 Nigbati ale de, nitoripe o je ojo ipale mo Sabati \v 43 Josefu ara Arimatia wa sibe. O je eniyan pataki ninu igbimo, oun si duro de ijoba Olorun. Olo si oda Pilatu pelu igboya lati bere fun ara Jesu. \v 44 Enu ya Pilatu pe Jesu ti ku; o pe ogagun-ogorun lati bii boya Jesu ti ku.