adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/29.txt

1 line
598 B
Plaintext

\v 29 Jésù wípé, lóòtọ́ ni mo wí fún yin, kò sí ẹni tí ó fi ilé, tàbí arákùnrin tàbí arábìnrin tàbí ìyá tàbí bàbá tàbí àwọn ọmọ tàbí ilẹ̀ nítorí tèmi àti nítorí ìyìn-rere \v 30 tí kì yóò gbàá ní ìlọ́po ọgọ́rùnún ní ayé yìí: ilé àti, arákùnrin, àti arábìnrin, àti ìyá àti àwọn ọmọ àti ilẹ̀ pẹ̀lú inúnibíni àti ní ayé tí ńbọ̀ iyè aìnípẹ̀kun. \v 31 , Ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ àwọn ẹni iwájú ní yóò di ẹni ẹ̀yìn àti ẹni ẹ̀yìn yóò sì di ẹni iwájú."