adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/26.txt

1 line
400 B
Plaintext

\v 26 Ẹnú sì yà wọ́n gidigidi wọ́n sì ńbá ara wọn sọ̀rọ̀, "taani yóò wá le là bá yì?" \v 27 Jésù wò wọ́n ó wípé, "pẹ̀lú ènìyàn ó sòro se sùgbọ́n kò rí bẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run. Nítorí ohun gbogbo ni síse fún Ọlọ́run." \v 28 Pétérù bẹ̀rẹ̀ sí báa sọ̀rọ̀, "wòó a ti fi ohun gbogbo sílẹ̀ a sì ti tẹ̀lé ọ."