adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/07.txt

1 line
462 B
Plaintext

\v 7 Lẹ́yìn naa Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sì lọ sí odò Gálílì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn sí tèlé wọn lati Gálílì ati lati Judia. \v 8 Láti Jerusalemu ati lati ilẹ̀ àwọn ará Édómù ati lati ẹ̀yìn odò Jódánì wa àti àgbègbè àwọn ará Tireni oun Sidoni wa. Ńigbá tí wọ́n sí gbọ́ àwọn ohun àrà tí à ń ti ọ́wọ rẹ̀ se ọ̀pọ́ àwọn ènìyàn tọọ wa.