adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/18.txt

1 line
563 B
Plaintext

\v 18 Ó sì se, àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí ngba àwẹ̀. Àwọn ènìyàn kan wá, wọ́n sì wí fún pe, "Kíló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí fi ngbawẹ, sùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yín rẹ ko gbàwẹ̀?" \v 19 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ó seése kí àwọn tì ó wá sí ibi ìgbéyàwó ma gbàwẹ̀ nígbàtí ọkọ ìyàwó sì wà pẹ̀lú wọn?" Níwọ̀n ìgbàtí wọn bá sì ní ọkọ ìyàwó larin wọn, kò seése fún wọn lati gbàwẹ̀.