adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/15.txt

1 line
534 B
Plaintext

\v 15 Jésù si njẹun nínú ilé Lefi àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ, wọn ba a jẹun pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sí wà níbẹ̀, wọ́n si ntọ lẹ́yìn. \v 16 Nígbàtí àwọn akọ̀wé, ti wọn jẹ́ Farisí, rí tí Jésù njẹun pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́sẹ̀ àti àwọn agbowó òde, wọ́n wí fún àwon ọmọ ẹ̀yìn rẹ pe, "Kíló sẹlẹ̀ tí O nfi bá àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ̀ jẹun?"