adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/10.txt

1 line
499 B
Plaintext

\v 10 Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní ayé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrò ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn, tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."