adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/08.txt

1 line
353 B
Plaintext

\v 8 Lójú ẹsẹ́ Jésù mọ ohun tí wọn nrò láàrin ara wọn nínú ọkàn rẹ. Ó wí fún wọn, "Kílódé tí ẹ̀yín fi nro èyí nínú ọkàn yin?" \v 9 Èwo ni ó rorùn jù láti wí fún ọkùnrin tí arọ náà, 'A dárí gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́' tàbí lati wípé 'Dìde, gbé ibùsùn rẹ kí o sì ma rìn?'