adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/03.txt

1 line
370 B
Plaintext

\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin arọ kan; ènìyàn mẹ́rin ni ó gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí ààyè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí arọ náà sùn sí.