adesinaabegunde_yo_mrk_text.../02/01.txt

1 line
299 B
Plaintext

\c 2 \v 1 Nígbàtí Ó padà sí Kápánámù lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, ó di mímọ̀ wípé Ó wà nínú ilé. \v 2 Ọ̀pọ̀lọọpọ̀ sì péjọ níbẹ̀ tóbẹ̀ tí kò fi sí ààyè mọ́, kò sí lẹ́nu ìlẹ̀kùn pẹ̀lú, Jésù sì bá wọn sọ ọ̀rọ̀ náà.