adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/29.txt

1 line
242 B
Plaintext

\v 29 Àwọn tó n kọjá lọ búu, wọ́n mi orí wọn wọ́n sì wípé, "Áha! Ìwọ́ tó fẹ́ wó tẹ́mpìlì kí osì tún kọ láàrin ọjọ́ mẹta, \v 30 gba ara rẹlà ki osì sọ̀kalẹ̀ láti orí àgbélèbú!"