adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/25.txt

1 line
388 B
Plaintext

\v 25 Ójẹ́ wákàtí kẹẹ̀ta ọjọ́ nigbàtí wọ́n kàán mọ́ àgbélèbú \v 26 Wọ́n kọ ẹ̀sùn rẹ̀ sí orí pátákó kan pé, "Ọba àwọn júù." \v 27 Wọ̀n kàn-án mọ́ àgbélèbú pẹ̀lú olè mèjí, ìkan ní ọwọ́ ọ̀tún àti ìkan ní ọwọ́ òsì \v 28 "Amú ìwé mímọ́ náà ṣẹ pé, 'Akàá pẹ̀lú àwọn arúfin.'