adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/22.txt

1 line
350 B
Plaintext

\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ sí ibi tí à ńpè ní Gọ́lgọ́tà (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ ńjé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjìá, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón Kàn-án mọ́ àgbélèbú nígbàtí wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn.