adesinaabegunde_yo_mrk_text.../15/06.txt

1 line
488 B
Plaintext

\v 6 Nísinsnìyí ni àsìkò àṣè, Pílátù máa ń fi ẹlẹ́wọ̀n kan lé wọn lọ́wọ́, ẹlẹ́wọ̀n tí wọ́n bá béèrè. \v 7 Ní ibẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọlọ́tẹ̀ nínu túbú, láàrin àwọn apànìyàn tí ó lọ́wọ́ nínú ọ̀tẹ̀, ni ọkùnrin tí à ń pè ní Bárábà wà. \v 8 Àwọn èrò náà wá sí ọ̀dọ̀ Pílátù, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí bi léèrè pé kí ó se oun tí ó tí n se tẹ́lẹ̀ fún wọn.