adesinaabegunde_yo_mrk_text.../16/01.txt

1 line
296 B
Plaintext

\c 16 \v 1 Nígbàtí ọjọ́ ìsinmi tí kọjá, Màríà Magdalénì àti Màríà ìya Jákọ́bù àti Salomíì mú tùràrí wá kí wón le kun ara Jésù. \v 2 Ní kété tí ilẹ̀ mó ní ọjó ìkíní ọ̀sẹ̀ wọ́n lọ sí ẹnu ibojì ní kẹ́tẹ́ tí òòrùn yọ.