adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/43.txt

1 line
448 B
Plaintext

\v 43 Ṣùgbọ́n kò gbọdọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàrín yín. Ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di gíga nínú yín yóò se ọmọ ọ̀dọ̀, \v 44 àti ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ se asájú nínú yín yóò se ìránsẹ́ gbogbo won. \v 45 Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá pé kí á se ìránsẹ́ fún òun bíkòse láti se ìránsẹ́ fún ẹlòmíràn àti láti yònda ara rẹ̀ fún ìràpàdà ọ̀pọ̀lọpọ̀."