adesinaabegunde_yo_mrk_text.../10/20.txt

1 line
531 B
Plaintext

\v 20 Okùnrin náà wípé, "Olùkọni, gbogbo ǹkan wọ̀nyí ni mo ti gbọ́ràn sí láti ìgbà tí mo ti wà ní ọ̀dọ́" \v 21 Jésù wòó ó sì fẹ́ẹ. Ó wí fún pé, " ohùn kan ni o kò ní. O gbọ́dọ̀ ta ohun gbogbo tí o ní, kí o sì fi fún àwọn aláìní, ìwọ yó sì ní ìsura ní ọ̀run. Lẹ́yìn náà wá, máa tẹ̀lé mi" \v 22 Sùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀ yí ojú rẹ̀ korò, ó sì lọ kúrò pèlú ìbànújẹ́ ọkàn, nítorí tí ó ní ọrọ̀ púpọ̀.