adesinaabegunde_yo_mrk_text.../09/04.txt

1 line
434 B
Plaintext

\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì ń bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ó sì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, Ẹ jẹ́ ká kọ́ ilé'gbe mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)