adesinaabegunde_yo_mrk_text.../08/35.txt

1 line
402 B
Plaintext

\v 35 Nítorí ẹni tó bá gbìyànjú láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là, yóò sọ ọ́ nù, ẹni tí ó bá sì sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù nítorí í tèmi àti nítorí ìhìnrere, òun náà ni yóò gbà á là. \v 36 Nítorí èrè kí ni ó jẹ́ fún ẹni tí ó jèrè gbogbo ayé, tí ó sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù? \v 37 Kí ni ènìyàn yóò fi ṣe pàṣípàrọ̀ ẹ̀mí rẹ̀?