adesinaabegunde_yo_mrk_text.../08/31.txt

1 line
425 B
Plaintext

\v 31 Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn pé, Ọmọ Ènìyàn kò le ṣàìmá jìyà ohun púpọ̀, a ó sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn àgbàgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, a ó sì pa á, lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta yóò sì jíǹde. \v 32 Ó sọ èyí láìfi ohunkóhun pamọ́ fún wọn. Pétérù pe Jésù sẹ́yìn, ó sì bẹ̀rẹ̀ si bá a wí.