adesinaabegunde_yo_mrk_text.../08/27.txt

1 line
377 B
Plaintext

\v 27 Jesu àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí àwọn abúlé ní agbègbè Kesaréà Fílípì. Lójú ọnà, ó bi àwọn ọmọ ẹyìn rẹ̀ pé, “Ta ni àwọn ènìyàn ń fi mí pè?” \v 28 Wọ́n dáhùn pé, “Jòhánù Onítẹ̀bọmi. Àwọn mìíràn wí pé, "Èlíjàh", àwọn míràn si wípé ọ̀kan nínú àwọn wòlíì."'