adesinaabegunde_yo_mrk_text.../08/11.txt

1 line
524 B
Plaintext

\v 11 NÍgbànáà ni àwọn Farisí jáde wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ń se àríyànjiyàn pẹ̀lú u rẹ̀. Wọ́n ń wá ààmì láti ọ̀run wá lọ́wọ̀ ọ rẹ̀, láti dán an wò. \v 12 Ó mí kanlẹ̀ ní ọkàn an rẹ̀ ó wípé, “Èéṣe tí ìran yìí fi ń wá ààmì? Lóòótọ́ ni mo wí fún un yín, kò si ààmì tí a ó fi fún ìran yín.” \v 13 Nígbà náà ni fi wọ́n sílẹ̀, ó padà sínú ọkọ̀ ojú omi, ó sì rékọjá sí apá kejì Òkun náà.