adesinaabegunde_yo_mrk_text.../03/20.txt

1 line
512 B
Plaintext

\v 20 Lẹ́yí èyí o lọ́ sí ilé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì kójọ lẹẹ̀kan si tó bẹ̀ tí wọn kòle ràyè fún oúnjẹ. \v 21 Nígbà tí àwọn ẹbí rẹ sì gbọ́ nípa ohun tió ń sẹlẹ̀, wọ́n jáde lati lọ mú nitórití wọ́n wípé "kò mọ ohún tió ń se." \v 22 Àwọn Akọ̀wé tí ó ti Jerusalemu wá wípé, "ẹ̀mí beélsébúbù ti gbé e wọ̀" àti wípé "nípa olórí àwọn ẹ̀mí òkùnkùn ni ó ń lé áwọn ẹ̀mí òkùnkùn jáde."