\v 11 Ńigbà kuú gbà tí àwọn ẹ̀mì aìmọ́ bá ri, wọn a tẹríba níwájú rẹ pẹ̀lú ariwo, wọn a wípé, "Ìwọ ni Ọmọ Olórun." \v 12 Ó sì pa wọn lẹ́nu mọ́ pé kí wọn máá se fi òun hàn.