\v 29 Ó sì bi wọ́n pé, “Ṣùgbọ́n ta ni ẹ̀yin ń fi mí pè?” Peteru dáhùn pé, “Ìwọ ni Kristi náà.” \v 30 Jesu kìlọ̀ fún wọn, kí wọn má sọ fún ẹnikẹ́ni nípa òun.