Thu May 20 2021 15:28:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 15:28:13 +01:00
parent 992d22abfd
commit f8309ce2fa
1 changed files with 2 additions and 0 deletions

2
12/38.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 38 Nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ Jésù wípé, “Ẹ ṣọ́ra fun àwọn olùkọ́ òfin, tí wọ́n fẹ́ láti máa wọ aṣọ gígùn káàkiri, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà \v 39 àti ibùjókòó ọlá nínú Sinagọgu àti ipò ọlá níbi àsè. \v 40 Àwọn tí wọ́n jẹ ilé àwọn opó rún, tí wọ́n sì ń gbàdúrà gígùn fún àṣehàn, nítorí èyí, ìjìyà wọn yóò pọ̀ púpọ̀.”
Ọ̀rẹ́ opó