diff --git a/15/22.txt b/15/22.txt index 870bf48..9420e99 100644 --- a/15/22.txt +++ b/15/22.txt @@ -1 +1 @@ -\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ sí ibi tí à ńpè ní Golgota (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ njé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjía, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón kàán mọ́ àgbélèbú, wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn. \ No newline at end of file +\v 22 Àwọn ọmọ ọgun náà mú Jésù lọ sí ibi tí à ńpè ní Gọ́lgọ́tà (èyí tí ìtumọ̀ rẹ̀ ńjé, "Ibi agbárí"). \v 23 Wọ́n fun ní wáínì tí a pò pẹ̀lú òjìá, sùgbọ́n kò muú \v 24 Wón Kàn-án mọ́ àgbélèbú, wọ́n sì sẹ́ gègé láti pín asọ rẹ̀ láàrin ara wọn. \ No newline at end of file