Tue May 18 2021 21:32:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 21:32:39 +01:00
parent 95614433c9
commit f18e29eb63
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ. Ó sì yọ ẹ̀ka ńlá níbi tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí, kí wọn sì rí ìdáàbòbò.”
\v 30 Ó sì tún wí pé, “Kí ni a ò bá fi ìjọba Ọlọ́run wé, tàbí òwe wo ni a lè fi ṣe àkàwé rẹ̀? \v 31 Ó dàbí èso hóró musitadi, nígbàt ó jọ ọ̀kan nínú àwọn èso tí ó kéré jùlọ ti a gbìn sínú ilẹ̀. \v 32 Síbẹ̀, nígbà tí a gbìn ín, ó dàgbàsókè, ó gbilẹ̀, ó sì di títóbi ju gbogbo ewéko inú ọgbà yòókù lọ, ó sì yọ ẹ̀ka ńlá, tóbẹ̀ tí àwọn ẹyẹ ọ̀run lè kọ́ ìtẹ́ wọn sí ìbòji rẹ kí wọn sì rí ìdáàbòbò.”