Wed Jun 26 2019 12:05:26 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 12:05:28 +01:00
parent b6abb8c587
commit ebf69ee499
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 42 Nígbàtí alẹ́ dé, nítorípé ó jẹ́ ọjọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún Sábátì \v 43 Jósẹ́fu ará Arimatia wá síbẹ̀. Ó jẹ́ ènìyàn pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ tón dúró de ìjọba Ọlọ́run. Ólọ sí ọ̀dọ Pilatu pẹ̀lù ìgboyà láti bèrè fún ara Jésù. \v 44 Ẹnú ya Pílátù pé Jésù ti kú; ó pe ògágun-ọgọ̀rún láti bií bóyá Jésù ti kú.
\v 42 Nígbàtí alẹ́ dé, nítorípé ó jẹ́ ọjọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún Sábátì \v 43 Jósẹ́fù ará Arimatia wá síbẹ̀. Ó jẹ́ ènìyàn pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ tó ń dúró de ìjọba Ọlọ́run. Ólọ sí ọ̀dọ Pílátù pẹ̀lù ìgboyà láti bèrè fún ara Jésù. \v 44 Ẹnú ya Pílátù pé Jésù ti kú; ó pe ògágun-ọgọ̀rún láti bií bóyá Jésù ti kú.