Thu May 20 2021 13:20:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 13:20:13 +01:00
parent 24681e723c
commit eb8446bc8a
3 changed files with 6 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Àwọn ọmọ ẹyìn sí bẹ̀rẹ̀ sí ronú èyí láàrín ara wọn wí pé, “Torí pé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni” \v 17 Jesu mọ ohun tí wọ́n sọ láàrín ara wọn, ó sì dá wọn lóhùn pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń ṣe àròyé pé ẹ̀yin kò mú àkàrà lọ́wọ́? Sé ẹ̀yin kò kíyèsi ni? Se kò tilẹ̀ yẹ yín ni? àbí ọkàn yín le ni.
\v 16 Àwọn ọmọ ẹyìn sí bẹ̀rẹ̀ sí ronú èyí láàrín ara wọn wí pé, “Torí pé a kò mú àkàrà lọ́wọ́ ni” \v 17 Jesu mọ ohun tí wọ́n sọ láàrín ara wọn, ó sì dá wọn lóhùn pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń ṣe àròyé pé ẹ̀yin kò mú àkàrà lọ́wọ́? Sé ẹ̀yin kò kíyèsi ni? Sé kò tilẹ̀ yẹ yín ni? Tàbí ọkàn ti rẹ̀wẹ̀sì?

3
08/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 18 Ẹ̀yin ní ojú, sé ẹ kò fi ríran? Ẹ̀ ni etí, ẹ kò sí gbọ́ran? Ẹ̀yin kò sì rántí? 19Nígbà ti mo bu ìṣù àkàrà márùn-ún fún ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (5,000) ènìyàn, agbọ̀n mélòó ni ó kún fún àjẹkù tí ẹ ṣàjọ?”
Wọ́n wí pé, “Méjìlá.”
\v 19 ss

View File

@ -78,6 +78,7 @@
"08-05",
"08-07",
"08-11",
"08-14"
"08-14",
"08-16"
]
}